Pasuma & Qdot – Omo Ologo Lyrics

Pasuma & Qdot – Omo Ologo Lyrics
Omo Ologo
Pasuma & Qdot
    Lyrics copied!
    Omo Ologo Album Art
    "Omo Ologo." - Pasuma & Qdot

    Album: Omo Ologo - Single
    Track No: 01
    Ọga nla ni ko ṣe farawe
    Ọmọ ọmọ Mọriamọ, Qdot lorukọ mi
    Them try make them block my way
    God pass them I don go far away
    Na God dey run am ko kan aye o
    Ọga nla ni ko ṣe farawe
    Wọn binu ọmọ ologo
    Awọn olofo wọn binu ọmọ ologo
    They be bad belle people, wọn binu ọmọ ologo
    They wan make your world their own
    Wọn binu ọmọ ologo
    Wọn binu ọmọ ologo
    Ọmọ ologo ko le logo
    Ma ba wọn binu ologo
    Oluwa lo mọ ologo
    Olofo lo n binu ologo
    Towo bade, tọla bade, ọrẹ le di ọta ẹni
    To ba di pe o dan tan, ẹbi le fẹ pani
    Ba ṣe n jẹlọ, wọn binu
    Bowo ṣe n wọle, wọn binu
    Ba ṣe n gbera, wọn binu
    Ba ṣe n gberi, wọn binu
    B'okiki ṣe pọ
    Wọn binu ọmọ ologo
    Awọn olofo wọn binu ọmọ ologo
    They be bad belle people, wọn binu ọmọ ologo
    They wan make your world their own
    Wọn binu ọmọ ologo
    Wọn binu ọmọ ologo
    Tẹ ba lajẹ ni iya yin, ajẹ niya temi naa
    Tẹ ba loṣo ni baba yin, oṣo ni baba temi naa
    Bẹ ni bibeli mo ni kurani, bẹ ni kurani mo ni bibeli
    Tẹ ba ni kinni baba yin, emi naa ni kinni baba mi
    Ẹ ri awọn onisọlẹnu wọn sọrọ bi Ọlọhun
    Wọn fẹ mọ idi abajọ mi wọn fẹ mọle baba alajọ mi
    Iya wọn binu, o ni pe o mọ ṣe pe oun o biru wa
    Lataye ligaligali to fi di gbayi o
    Wọn binu ọmọ ologo
    Awọn olofo wọn binu ọmọ ologo
    They be bad belle people, wọn binu ọmọ ologo
    They wan make your world their own
    Wọn binu ọmọ ologo
    Wọn binu ọmọ ologo
    Them try make them block my way o
    God pass them I don go far away
    Na God dey run am ko kan aye
    Ọga nla ni ko ṣe farawe
    Wọn binu ọmọ ologo
    Awọn olofo wọn binu ọmọ ologo
    Dey be bad belle people wọn binu ọmọ ologo
    They wan make their world o
    Wan binu ọmọ ologo
    Wan binu ọmọ ologo
    A jọ n ronu, a jọ n dunnu, lojiji lo di p'ọn binu
    Ara n ta wọn ba ṣe n gberi
    Lojiji lo di p'ọn leri
    Leri leka abosi
    A fọrọ wọn mu Hennessey
    Ko saye fun alabosia
    Ọlọtẹ lo ma ṣẹsin ah
    Ọga wa, Anọbi Ọmọle
    Ọmọ iyawo Anọbi
    Afunnilounjẹ ma wo'bẹ
    Alagbe to n fun alagbe lowo
    Eeyan IBD Dende, eh eh eh eh

    Writer(s): Pasuma & Qdot.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Omo Ologo

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!