"Ọmọ Mí Òwón." - Brymo
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Bàbá rẹ ò gbọ̀n tóó
Dáríjì mí o
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Kò sẹnì gbọn jù Ọlọ́run lọ
Ṣé bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Òrìṣà òkè
Oh, eh, Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọlú ọ̀run gan-an ò gbọ́n tó
Kò sí bo ṣe ṣe tó ma t'ènìyàn
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Kò s'ẹ́ni gbọ́n ju Ọlú ọ̀run lọ
Ṣe bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Bò n là kàkà
Àwọn alaálè
Wọn ò ní f'orí j'ọ̀ṣíká
A ò ṣè kà
A ò parọ́
A ò parọ́ o
Ah, a ma là
A ma là
A ma là
Writer(s): Ọláwálé Ọlọ́fọ̀’rọ̀.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.
Subscribe now and never miss a new song lyric update.
Ọmọ Mí Òwón