"disco." - FOLA & Young Jonn
I'll run kilometers, if you are very far, ah
Stay on key, do-re-mi-fa ah
Even bo lọ America
Ṣo mọ pe o má n dùn when you bọ s'inú iyára?
O joromijo, do me jara
Amdallah, you're my desire
Ah, gbogbo
Gbogbo
Gbogbo bo ṣe n jo disco
Ye, mo r'ogo
I can't lie, bó ṣe n ṣe ni slo-mo
Make me loco
So'di wùké, your body wicked
Loving you is unlimited, oh-ah
To ba wa mi wa'le
O kuku ni sọ
Ah, ma lọ ba mi ja, ay
Olufunmi, jọọ ọ
Ma lọ ma gbé mi sáré
Lo side àwọn Chibuzor ọ-ọ, ah
'Cause of Veronica, ma-ma ba mi ja
Ibadi ṣa ni, ṣa n'ìjo wa
You fit dey under my umbrella
And I won't do the things that you don't like
Anything you say, girl, I won't mind
Your body ṣa n'ìjo wa
B'áwọn body, ṣo wa?
Oló mi ma lera
And I promise you to do better
O ya, gbogbo
Gbogbo
Gbogbo bo ṣe n jo disco
Ye, mo r'ogo
I can't lie, bó ṣe n ṣe ni slo-mo
Make me loco
I'm so addicted, your body wicked
Loving you is unlimited, oh-ah
To ba wa mi wa'le
O kuku ni sọ
Ah, ma lọ ba mi ja, ay
Olufunmi, jọọ ọ
Ma lọ ma gbé mi sáré
Lo side àwọn Chibuzor ọ-ọ, ah
'Cause of Veronica, ma-ma ba mi ja
Ibadi, ibadi, ṣa n'ìjo wa
Pounds sterling, o wa
And I won't do the things that you don't like
Ṣebi ibadi, your body ṣa n'ijo wa
You fit dey under my umbrella
Ṣo like Porsche Panamera?
Writer(s): Afolarin Temiloluwa Odunlami & John Udomboso.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.