Lil Kesh – Shoki (Remix) [feat. Davido & Olamide] [Male Version] Lyrics

Lil Kesh – Shoki (Remix) [feat. Davido & Olamide] [Male Version] Lyrics
Shoki (Remix) [Male Version]
Lil Kesh (feat. Davido & Olamide)
    Lyrics copied!
    Shoki (Remix) [Male Version] Album Art
    "Shoki (Remix) [Male Version]." - Lil Kesh (feat. Davido & Olamide)

    Album: Shoki (Remix) [Male Version] [feat. Davido & Olamide] - Single
    Track No: 01
    It's Davido
    OBO, baddest
    Kesh
    HKN Gang, YBNL, ṣọki
    Lagos city
    Lil kesh
    Number one, number one
    O ya show me ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    Everybody ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    Every person ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    Everybody dey ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    O ya show me ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    Everybody ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    O ya ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    Make we ṣọki
    Ṣọki ṣọki
    And I am looking for that shawty
    With the baddest ṣọki
    When everybody dey ṣọki
    Abi you still dey look for Johnny
    O but if you get case for body
    Di time wen we go make you dey ṣọki
    Make we please no stop it
    I wanna see you drop it now
    For me now
    On this ground
    O ya dahun
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki
    Wọn lewo mo gbe de yii ah?
    Ẹjọ ijo ṣọki l'eleyi ah
    Ẹjọ ijo igboro l'eleyi ah
    Anywhere awọn butty le jo si no problem
    Nawọ siwaju
    K'ejika ma lọ sọtun, sosi
    Ma fo soke diẹdiẹ
    O ṣe o ya fakọ si, o ya fakọ si
    Oya ṣọki ki n ṣọki (Ah)
    In the club anything we are popping (Ah)
    Ba mi wọmọ to sexy o jare (Ah)
    Ko wa jo ṣọki fun mi o jare no problem
    Joo ki n ṣọki (Ah)
    In the club anything we are popping (Ah)
    Ba mi wọmọ to sexy o jare (Ah)
    Ko wa jo ṣọki fun mi o jare eh o jare ah
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki
    Aunty Tope, Timileyin
    Kini buruku re e tẹ gbe sẹyin
    Ki lo wa n ti yin loju
    Kẹ jo ṣọki ẹ n fọwọ boju
    Furọ rabata we tẹ ku gbe wa saye
    Ma lo ja bata ye mi o ma le ṣalaye
    Bere lọwọ Taye mo ti romata we
    Onion butty ni ko ṣe e fata we
    Ah, ṣọki da?
    E wo T-bills aunty wa eh
    Wọn o ni gba
    Nibi tawọn alanti wa
    O ya jẹ n pọnke
    Ah, ṣọki ki n ṣọki, ki n ma wa ẹ wale mọ
    O ya jẹ n pọnke
    Ah ṣọki n ṣọki ka dẹ ma pade mọ
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki
    O ya ṣọki ki n ṣọki ah
    Ba mi wọmọge to ba yọdi ah
    Mi o ni ko wa twerk ko wa gbọndi ah
    All I want her to do is to ṣọki
    Ṣọki ki n ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki ah ah ṣọki
    Ṣọki
    It's Davido (Ṣọki, ṣọki)
    (Ṣọki)
    Lil Kesh (Ṣọki, ṣọki, all I want her to do is to ṣọki)
    (Ṣọki)
    Bado
    (Ṣọki, ṣọki)
    YBNL, HKN Gang (Ṣọki, ṣọki, all I want her to do is to ṣọki)
    Baba iya eeyan

    Writer(s): Davido, Lil Kesh & Olamide.

    All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders. No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.

    Get the Latest Lyrics Updates!

    Subscribe now and never miss a new song lyric update.

    Failed to load audio, please try again later.
    Failed to load song data.
    Invalid email address entered!
    Enter your suggestion!
    Thanks for your suggestion!
    Link copied
    Stop & exit Playlist

    Suggest a Lyrics Edit

    Stop Song
    Rhyto-Artwork

    Shoki (Remix) [Male Version]

    Rhyto
    × Add Rhyto to your Home Screen!