Ode Iya Tawa, ta lọ oh
Mọin‐mọin sunkun ororo
Akara n ṣe bi ẹkọ lọ o
Mọin‐mọin sunkun ororo
Ojo n rọ
Ṣere n inu'le, mo ti sọ pe ma lọ wọnu ojo
Ojo n rọ
Ṣere n inu'le, mo ti sọ pe ma lọ wọnu ojo
Ṣẹrẹ, Erele, Ẹrẹna
Igbe, Ebibi, Okudu, Agẹmọ, Ogun, Ọwẹrẹ
Ohun la fi n ṣọpẹ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'ọn ma fi mi ṣakọ
K'awọn girls ma fi mi demo
Sọ fun wọn boys ma fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'awọn boy fi mi ṣakọ o
Talo ma fi mi ṣakọ?
Damọla fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'ọn ma fi mi ṣakọ
K'awọn girls ma fi mi demo
Sọ fun wọn boys ma fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'awọn boy fi mi ṣakọ o
Talo ma fi mi ṣakọ?
Damọla fi mi ṣakọ
Bumper
K'ẹlomi bomb ah, k'ẹlomi bomb ah
Bumpеr
I no be Stevie Wondеr, I no be Stevie Wonder
Sọ fun wọn pe, "Baby, I'm younger and stronger, still getting younger"
Ọmọ nla, dem no fit do beyond that, dem no fit do beyond that
Mo n fowo wẹ
Bolaji lo laye sẹ
Awa gan-an gan-an la n jaye sẹ
Ki lo wa de, ko kan aye sẹ, ko kan aye
A n fowo wẹ
Bolaji lo laye sẹ
Awa gan-an gan-an la n jaye sẹ
Ki lo wa de, ko kan aye sẹ, ko kan aye
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'ọn ma fi mi ṣakọ
K'awọn girls ma fi mi demo
Sọ fun wọn boys ma fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'awọn boy fi mi ṣakọ o
Talo ma fi mi ṣakọ?
Damọla fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'ọn ma fi mi ṣakọ
K'awọn girls ma fi mi demo
Sọ fun wọn boys ma fi mi ṣakọ
Mo ni ko wo mi bi mo ṣe n demo
K'awọn boy fi mi ṣakọ o
Talo ma fi mi ṣakọ?
Damọla fi mi ṣakọ
Bumper
K'ẹlomi bomb ah, k'ẹlomi bomb ah
Bumpеr
I no be Stevie Wondеr, I no be Stevie Wonder
Sọ fun wọn pe, "Baby, I'm younger and stronger, still getting younger"
Ọmọ nla, dem no fit do beyond that, dem no fit do beyond that
Writer(s):
DJ Tunez, Wande Coal.
All lyrical content displayed on this website is the intellectual property of its respective copyright holders.
No ownership is implied, and no copyright infringement is intended.